大卫的子孙
1以下是大卫在希伯仑生的儿子:长子暗嫩,由耶斯列人亚希暖所生;次子但以利,由迦密人亚比该所生; 2三子押沙龙,由基述王达买的女儿玛迦所生;四子亚多尼雅,由哈及所生; 3五子示法提雅,由亚比她所生;六子以特念,由大卫的妻子以格拉所生。 4以上六人都是大卫在希伯仑生的。大卫在希伯仑做王七年零六个月,在耶路撒冷做王三十三年。 5大卫在耶路撒冷生的儿子有示米亚、朔罢、拿单和所罗门,这四个儿子的母亲是亚米利的女儿拔示芭。 6大卫的儿子还有益辖、以利沙玛、以利法列、 7挪迦、尼斐、雅非亚、 8以利沙玛、以利雅大和以利法列,共九人。 9这些都是大卫的儿子,不包括嫔妃生的儿子。大卫还有个女儿,名叫她玛。
所罗门的后裔
10所罗门的儿子是罗波安,罗波安的儿子是亚比雅,亚比雅的儿子是亚撒,亚撒的儿子是约沙法, 11约沙法的儿子是约兰,约兰的儿子是亚哈谢,亚哈谢的儿子是约阿施, 12约阿施的儿子是亚玛谢,亚玛谢的儿子是亚撒利雅,亚撒利雅的儿子是约坦, 13约坦的儿子是亚哈斯,亚哈斯的儿子是希西迦,希西迦的儿子是玛拿西, 14玛拿西的儿子是亚们,亚们的儿子是约西亚。 15约西亚的儿子有长子约哈难、次子约雅敬、三子西底迦、四子沙龙。 16约雅敬的儿子是耶哥尼雅和西底迦。
耶哥尼雅的后裔
17被掳的耶哥尼雅的儿子是撒拉铁、 18玛基兰、毗大雅、示拿萨、耶加米、何沙玛、尼达比雅。 19毗大雅的儿子是所罗巴伯和示每。所罗巴伯的儿子是米书兰和哈拿尼雅,女儿是示罗密, 20他还有五个儿子:哈舒巴、阿黑、比利迦、哈撒底、于沙·希悉。 21哈拿尼雅的儿子是毗拉提和耶筛亚。耶筛亚生利法雅,利法雅生亚珥南,亚珥南生俄巴底亚,俄巴底亚生示迦尼, 22示迦尼的儿子是示玛雅,示玛雅的儿子是哈突、以甲、巴利亚、尼利雅、沙法。 23尼利雅的三个儿子是以利约乃、希西迦和亚斯利干。 24以利约乃的七个儿子是何大雅、以利亚实、毗莱雅、阿谷、约哈难、第莱雅和阿拿尼。
Àwọn ọmọ Dafidi
13.1-9: 2Sa 3.2-5; 5.14-16; 1Ki 14.3-6.Àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ Dafidi tí a bí fún un ní Hebroni:
Àkọ́bí sì ni Amnoni ọmọ Ahinoamu ti Jesreeli;
èkejì sì ni Daniẹli ọmọ Abigaili ará Karmeli;
2Ẹ̀kẹta sì ni Absalomu ọmọ Maaka ọmọbìnrin Talmai ọba Geṣuri bí fún un;
ẹ̀kẹrin sì ni Adonijah ọmọ Haggiti;
3Ẹ̀karùnún ni Ṣefatia láti ọ̀dọ̀ Abitali;
àti ẹ̀kẹfà, Itreamu, láti ọ̀dọ̀ Egla aya rẹ̀.
43.4: 2Sa 5.4,5.Àwọn mẹ́fà wọ̀nyí ni a bí fún Dafidi ni Hebroni, níbi tí ó ti jẹ ọba fún ọdún méje àti oṣù mẹ́fà.
Dafidi sì jẹ ọba ní Jerusalẹmu fún ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n (33). 5Wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un ní Jerusalẹmu:
Ṣimea, Ṣobabu, Natani àti Solomoni. Àwọn mẹ́rin wọ̀nyí sì ni a bí láti ọ̀dọ̀ Bati-Ṣua ọmọbìnrin Ammieli.
6Ibhari sì wà pẹ̀lú, Eliṣama, Elifeleti, 7Noga, Nefegi, Jafia, 8Eliṣama, Eliada àti Elifeleti mẹ́sàn-án ni wọ́n.
9Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dafidi yàtọ̀ sí àwọn ọmọ tí àlè bí fún un. Tamari sì ni arábìnrin wọn.
Àwọn ọba Juda
10Ọmọ Solomoni ni Rehoboamu,
Abijah ọmọ rẹ̀,
Asa ọmọ rẹ̀,
Jehoṣafati ọmọ rẹ̀,
11Jehoramu ọmọ rẹ̀,
Ahasiah ọmọ rẹ̀,
Joaṣi ọmọ rẹ̀,
12Amasiah ọmọ rẹ̀,
Asariah ọmọ rẹ̀,
Jotamu ọmọ rẹ̀,
13Ahasi ọmọ rẹ̀,
Hesekiah ọmọ rẹ̀,
Manase ọmọ rẹ̀,
14Amoni ọmọ rẹ̀,
Josiah ọmọ rẹ̀.
15Àwọn ọmọ Josiah:
Àkọ́bí ọmọ rẹ̀ ni Johanani,
èkejì ọmọ rẹ̀ ni Jehoiakimu,
ẹ̀kẹta ọmọ rẹ̀ ni Sedekiah,
ẹ̀kẹrin ọmọ rẹ̀ ni Ṣallumu.
16Àwọn ìran ọmọ Jehoiakimu:
Jekoniah ọmọ rẹ̀,
àti Sedekiah.
Ìdílé ọba lẹ́yìn ìgbèkùn
17Àwọn ọmọ Jekoniah tí a mú ní ìgbèkùn:
Ṣealitieli ọmọ rẹ̀ ọkùnrin, 18Malkiramu, Pedaiah, Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama àti Nedabiah.
19Àwọn ọmọ Pedaiah:
Serubbabeli àti Ṣimei.
Àwọn ọmọ Serubbabeli:
Meṣullamu àti Hananiah. Ṣelomiti ni arábìnrin wọn. 20Àwọn márùn-ún mìíràn sì tún wà: Haṣuba, Oheli, Berekiah, Hasadiah àti Jusabhesedi.
21Àwọn ọmọ Hananiah:
Pelatiah àti Jeṣaiah, àti àwọn ọmọ Refaiah, ti Arnani, ti Ọbadiah àti ti Ṣekaniah.
22Àwọn ọmọ Ṣekaniah:
Ṣemaiah àti àwọn ọmọ rẹ̀: Hattusi, Igali, Bariah, Neariah àti Ṣafati, mẹ́fà ni gbogbo wọn.
23Àwọn ọmọ Neariah:
Elioenai; Hesekiah, àti Asrikamu, mẹ́ta ni gbogbo wọn.
24Àwọn ọmọ Elioenai:
Hodafiah, Eliaṣibu, Pelaiah, Akkubu, Johanani, Delaiah àti Anani, méje sì ni gbogbo wọn.