Daily Manna for Thursday, September 22, 2022

Daily Manna is a daily Bible devotional service provided by Biblica. The Scripture is provided in many forms and is new every day. It is a great way to receive the encouragement and hope found in the Word of God.

Verse of the Day

Isaiah 43:18-21

“Gbàgbé àwọn ohun àtẹ̀yìnwá;

má ṣe gbé nínú ohun àtijọ́.

Wò ó, Èmi ń ṣe ohun tuntun!

Nísinsin yìí ó ti yọ sókè; àbí o kò rí i bí?

Èmi ń ṣe ọ̀nà kan nínú aṣálẹ̀

àti odò nínú ilẹ̀ ṣíṣá.

Àwọn ẹhànnà ẹranko bọ̀wọ̀ fún mi,

àwọn ajáko àti àwọn òwìwí,

nítorí pé mo pèsè omi nínú aṣálẹ̀

àti odò nínú ilẹ̀ sísá,

láti fi ohun mímu fún àwọn ènìyàn mi, àyànfẹ́ mi,

àwọn ènìyàn tí mo dá fún ara mi

kí wọn kí ó lè kéde ìyìn mi.