1 Kronika 1 – YCB & KLB

Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn

1 Kronika 1:1-54

Ìran Adamu títí de Abrahamu

Títí dé ọmọkùnrin Noa

11.1-53: Gẹ 5; 10; 11; 25; 36.Adamu, Seti, Enoṣi,

2Kenani, Mahalaleli, Jaredi,

3Enoku, Metusela, Lameki,

Noa.

4Àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti.

Àwọn Ọmọ Jafeti

5Àwọn ọmọ Jafeti ni:

Gomeri, Magogu, Madai; Jafani, Tubali, Meṣeki àti Tirasi.

6Àwọn ọmọ Gomeri ni:

Aṣkenasi, Rifati àti Togarma.

7Àwọn ọmọ Jafani ni:

Eliṣa, Tarṣiṣi, Kittimu, àti Dodanimu.

Àwọn ọmọ Hamu

8Àwọn ọmọ Hamu ni:

Kuṣi, Ejibiti, Puti, àti Kenaani.

9Àwọn ọmọ Kuṣi ni:

Seba, Hafila, Sabta, Raama, àti Sabteka.

Àwọn ọmọ Raama:

Ṣeba àti Dedani.

10Kuṣi sì bí Nimrodu

ẹni tí ó di alágbára jagunjagun ní ayé.

11Ejibiti sì bí

Ludimu, Anamimu, Lehabimu, Naftuhimu, 12Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu.

13Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀,

àti Heti, 14àti àwọn ará Jebusi, àti àwọn ará Amori, àti àwọn ará Girgaṣi, 15àti àwọn ará Hifi, àti àwọn ará Arki, àti àwọn ará Sini, 16àti àwọn ará Arfadi, àti àwọn ará Semari, àti àwọn ará Hamati.

Àwọn ará Ṣemu.

17Àwọn ọmọ Ṣemu ni:

Elamu, Aṣuri, Arfakṣadi, Ludi àti Aramu.

Àwọn ọmọ Aramu:

Usi, Huli, Geteri, àti Meṣeki.

18Arfakṣadi sì bí Ṣela,

Ṣela sì bí Eberi.

19Eberi sì bí ọmọ méjì:

ọ̀kan ń jẹ́ Pelegi, nítorí ní ìgbà ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ̀ ya; orúkọ arákùnrin rẹ̀ ni Joktani.

20Joktani sì bí

Almodadi, Ṣelefi, Hasarmafeti, Jera. 21Hadoramu, Usali, Dikla, 22Ebali, Abimaeli, Ṣeba. 23Ofiri, Hafila, àti Jobabu. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Joktani.

24Ṣemu, Arfakṣadi, Ṣela,

25Eberi, Pelegi. Reu,

26Serugu, Nahori, Tẹra,

27àti Abramu (tí ń ṣe Abrahamu).

Ìdílé Abrahamu

28Àwọn ọmọ Abrahamu: Isaaki àti Iṣmaeli.

Àwọn ọmọ Hagari

29Èyí ni àwọn ọmọ náà:

Nebaioti àkọ́bí Iṣmaeli: Kedari, Adbeeli, Mibsamu, 30Miṣima, Duma, Massa, Hadadi, Tema, 31Jeturi, Nafiṣi, àti Kedema.

Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Iṣmaeli.

Àwọn ọmọ Ketura

32Àwọn ọmọ Ketura, obìnrin Abrahamu:

Simrani, Jokṣani Medani, Midiani Iṣbaki àti Ṣua.

Àwọn ọmọ Jokṣani:

Ṣeba àti Dedani.

33Àwọn ọmọ Midiani:

Efani, Eferi, Hanoku, Abida àti Eldaa.

Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ìran Ketura.

Àwọn Ìran Sara

34Abrahamu sì jẹ́ baba Isaaki.

Àwọn ọmọ Isaaki:

Esau àti Israẹli.

Àwọn ọmọ Esau

35Àwọn ọmọ Esau:

Elifasi, Reueli, Jeuṣi, Jalamu, àti Kora.

36Àwọn ọmọ Elifasi:

Temani, Omari, Sefi, Gatamu àti Kenasi;

láti Timna: Amaleki.

37Àwọn ọmọ Reueli:

Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa.

Àwọn ènìyàn Seiri ní Edomu

38Àwọn ọmọ Seiri:

Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, Diṣoni, Eseri àti Diṣani.

39Àwọn ọmọ Lotani:

Hori àti Homamu: Timna sì ni arábìnrin Lotani.

40Àwọn ọmọ Ṣobali:

Afiani, Manahati, Ebali, Ṣefo àti Onamu.

Àwọn ọmọ Sibeoni:

Aiah àti Ana.

41Àwọn ọmọ Ana:

Diṣoni.

Àwọn ọmọ Diṣoni:

Hemdani, Eṣbani, Itrani, àti Kerani.

42Àwọn ọmọ Eseri:

Bilhani, Saafani àti Akani.

Àwọn ọmọ Diṣani:

Usi àti Arani.

Àwọn alákòóso Edomu

43Àwọn wọ̀nyí ni ọba tí ó jẹ ní Edomu, kí ó tó di pé ọba kankan jẹ lórí Israẹli:

Bela ọmọ Beori, orúkọ ìlú rẹ̀ ni Dinhaba.

44Nígbà tí Bela kú, Jobabu ọmọ Sera ti Bosra sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

45Nígbà tí Jobabu kú, Huṣamu láti ilẹ̀ Temani sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

46Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi ọmọ Bedadi tí ó kọlu Midiani ní ìgbẹ́ Moabu, ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Afiti.

47Nígbà tí Hadadi sì kú, Samla láti Masreka, ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

48Samla sì kú, Saulu ti Rehoboti létí odò sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

49Nígbà tí Saulu kú, Baali-Hanani, ọmọ Akbori jẹ ọba ní ipò rẹ̀.

50Nígbà tí Baali-Hanani kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Pau; orúkọ ìyàwó sì ni Mehetabeeli ọmọbìnrin Matiredi, ọmọbìnrin Mesahabu. 51Hadadi sì kú pẹ̀lú.

Àwọn baálẹ̀ Edomu ni:

baálẹ̀ Timna, baálẹ̀ Alfa, baálẹ̀ Jeteti 52baálẹ̀ Oholibama, baálẹ̀ Ela, baálẹ̀ Pinoni. 53Baálẹ̀ Kenasi, baálẹ̀ Temani, baálẹ̀ Mibsari, 54Magdieli àti Iramu.

Àwọn wọ̀nyí ni baálẹ̀ Edomu.

Korean Living Bible

역대상 1:1-54

아담에서 아브라함까지

11:1 암시됨.인류 최초의 조상들은 아담, 셋, 에노스,

2게난, 마할랄렐, 야렛,

3에녹, 므두셀라, 라멕, 노아였으며

4노아의 아들은 셈, 함, 야벳이었다.

5야벳의 아들은 고멜, 마곡, 마대, 야완, 두발, 메섹, 디라스였으며

6고멜의 아들은 아스그나스, 리밧, 도갈마였고

7야완의 아들은 엘리사, 다시스, 깃딤, 1:7 창10:4에는 ‘도다님’로다님이었다.

8함의 아들은 구스, 미스라임, 붓, 가나안이며

9구스의 아들은 스바, 하윌라, 삽다, 라아마, 삽드가이고 라아마의 아들은 스바와 드단이었다.

10또 구스에겐 니므롯이라는 아들이 있었는데 그는 세상에서 최초의 1:10 또는 ‘영걸’정복자였다.

11그리고 미스라임의 아들은 루딤, 아나밈, 르하빔, 납두힘,

12바드루심, 갑도림, 가슬루힘이었으며 이 가슬루힘은 블레셋 사람의 조상이 되었다.

13또 맏아들 시돈과 그리고 헷을 낳은 가나안은

14여부스족, 아모리족, 기르가스족,

15히위족, 알가족, 신족,

16아르왓족, 스말족, 하맛족의 조상이 되었다.

17셈의 아들은 엘람, 앗수르, 아르박삿, 룻, 아람이며 아람의 아들은 우스, 훌, 게델, 메섹이었다.

18그리고 아르박삿의 아들은 셀라였고 셀라의 아들은 에벨이었다.

19에벨은 두 아들을 낳아 그 중 하나의 이름을 벨렉이라 하였다. 이것은 그 당시에 세상 사람들이 나누어졌기 때문이었다. 그리고 벨렉의 동생은 욕단이었다.

20욕단의 아들은 알모닷, 셀렙, 하살마, 예라,

21하도람, 우살, 디글라,

22에발, 아비마엘, 스바,

23오빌, 하윌라, 요밥이었다.

24셈에서 아브라함까지의 족보는 셈, 아르박삿, 셀라,

25에벨, 벨렉, 르우,

26스룩, 나홀, 데라,

27아브람 곧 아브라함의 순서로 되어 있다.

아브라함의 후손들

28아브라함의 아들은 이삭과 이스마엘이었으며

29이스마엘의 아들은 맏아들 느바욧, 둘째 게달, 그리고 앗브엘, 밉삼,

30미스마, 두마, 맛사, 하닷, 데마,

31여둘, 나비스, 게드마였다.

32아브라함에게는 그두라라는 첩이 있었다. 그녀가 낳은 아들은 시므란, 욕산, 므단, 미디안, 이스박, 수아였으며 욕산의 아들은 스바와 드단이었다.

33그리고 미디안의 아들은 에바, 에벨, 하녹, 아비다, 엘다아였다.

34아브라함의 아들 이삭에게는 두 아들이 있었는데 그들은 에서와 1:34 또는 ‘이스라엘’야곱이었으며

35에서의 아들은 엘리바스, 르우엘, 여우스, 얄람, 고라였다.

36그리고 엘리바스의 아들은 데만, 오말, 1:36 창36:15에는 ‘스보’스비, 가담, 그나스, 딤나, 아말렉이었으며

37르우엘의 아들은 나핫, 세라, 삼마, 밋사였다.

에돔의 원주민들과 왕들

38세일의 아들은 로단, 소발, 시브온, 아나, 디손, 에셀, 디산이며

39로단의 아들은 호리와 호맘이었고 로단의 누이는 딤나였다.

40소발의 아들은 알랸, 마나핫, 에발, 스비, 오남이며 시브온의 아들은 아야와 아나였다.

41그리고 아나의 아들은 디손이며 디손의 아들은 하므란, 에스반, 이드란, 그란이고

42에셀의 아들은 빌한, 사아완, 야아간이며 디산의 아들은 우스와 아란이었다.

43이스라엘에 왕이 있기 전에 에돔 땅을 다스린 왕들을 순서대로 열거하면 다음과 같다: 딘하바 사람인 브올의 아들 벨라,

44보스라 사람인 세라의 아들 요밥,

45데만 지방 출신인 후삼,

46모압 들에서 미디안족을 친 아윗 출신 브닷의 아들 하닷,

47마스레가 출신 삼라,

48강변에 위치한 르호봇 출신인 사울,

49악볼의 아들인 바알 – 하난,

50그리고 바이 출신 하닷이었는데 그의 아내는 메사합의 손녀이며 마드렛의 딸인 므헤다벨이었다.

51-54하닷이 죽은 후에 에돔 사람들은 여러 부족으로 나누어졌으며 그 족장들은 딤나, 1:51-54 창36:40에는 ‘알와’알랴, 여뎃, 오홀리바마, 엘라, 비논, 그나스, 데만, 밉살, 막디엘, 그리고 이람이었다.