1 Kọrinti 16 – YCB & NUB

Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn

1 Kọrinti 16:1-24

Ìkójọpọ̀ fún àwọn ènìyàn Ọlọ́run

116.1: Ap 24.17.Ǹjẹ́ ní ti ìdáwó fún àwọn ènìyàn mímọ́, bí mo tí wí fún àwọn ìjọ Galatia, bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ní kí ẹ ṣe. 216.2: Ap 20.7; 2Kọ 9.4-5.Ní ọjọ́ kìn-ín-ní ọ̀sẹ̀, kí olúkúlùkù yín fi sínú ìṣúra lọ́dọ̀ ara rẹ̀ ni apá kan, gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run ti ṣe rere fún ún, ki ó má ṣe si ìkójọ nígbà tí mo bá dé. 316.3: 2Kọ 8.18-19.Àti nígbà ti mo bá dé, àwọn ẹni tí ẹ bá yàn, àwọn ni èmi ó rán láti mú ẹ̀bùn yín gòkè lọ si Jerusalẹmu. 4Bí ó bá sì yẹ kí èmí lọ pẹ̀lú, wọn ó sì bá mi lọ.

Ìbéèrè ti ara ẹni

516.5: Ro 15.26; Ap 19.21.Ṣùgbọ́n èmi yóò tọ̀ yin wá, nígbà tí èmí bá ti kọjá láàrín Makedonia: nítorí èmi yóò kọjá láàrín Makedonia. 6Bóyá èmi ó sì dúró pẹ̀lú yín, tàbí kí n tilẹ̀ lo àkókò òtútù, ki ẹ̀yin lé sìn mí ni ọ̀nà àjò mí, níbikíbi tí mo bá ń lọ. 716.7: Ap 18.21.Nítorí èmi kò fẹ́ kan ri yín kí èmi sì ṣe bẹ́ẹ̀ kọjá lọ; nítorí èmi ń retí àti dúró lọ́dọ̀ yín díẹ̀, bí Olúwa bá fẹ́. 816.8: Ap 18.19.Ṣùgbọ́n èmi yóò dúró ni Efesu títí dí Pentikosti. 916.9: Ap 19.9.Nítorí pé ìlẹ̀kùn ńlá láti ṣe iṣẹ́ gidi ṣí sílẹ̀ fún mí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì ni àwọn ọ̀tá tí ń bẹ.

1016.10: Ap 16.1.Ǹjẹ́ bí Timotiu bá dé, ẹ jẹ́ kí ó wà lọ́dọ̀ yín láìbẹ̀rù, nítorí òun ń ṣé iṣẹ́ Olúwa, bí èmi pẹ̀lú ti ń ṣe. 11Nítorí náà kí ẹnikẹ́ni má ṣe kẹ́gàn rẹ̀. Ṣùgbọ́n ẹ sín ín jáde lọ́nà àjò ni àlàáfíà, kí òun lè tọ̀ mí wá; nítorí tí èmí ń fi ojú sí ọ̀nà fún wíwá rẹ̀ pẹ̀lú àwọn arákùnrin.

1216.12: Ap 18.24.Ṣùgbọ́n ní ti Apollo arákùnrin wa, mo bẹ̀ ẹ́ púpọ̀ láti tọ̀ yín wá pẹ̀lú àwọn arákùnrin, ṣùgbọ́n kì í ṣe ìfẹ́ rẹ̀ rárá láti wà nísinsin yìí, ṣùgbọ́n òun yóò wá nígbà tí ààyè bá ṣí sílẹ̀ fún un.

1316.13: Sm 31.24; Ef 6.10.Ẹ máa ṣọ́ra, ẹ dúró ṣinṣin nínú ìgbàgbọ́, ẹ ṣe bi ọkùnrin tí ó ní ìgboyà, ẹ jẹ́ alágbára. 14Ẹ máa ṣe ohun gbogbo nínú ìfẹ́.

15Ǹjẹ́ mo bẹ̀ yín ará, ẹ ṣá mọ ilé Stefana pé, àwọn ni ẹni àkọ́kọ́ tó gba Jesu ní Akaia, àti pé, wọn sì tí fi ará wọn fún iṣẹ́ ìránṣẹ́ àwọn ènìyàn mímọ́. 16Kí ẹ̀yin tẹríba fún irú àwọn báwọ̀nyí, àti fún olúkúlùkù olùbáṣiṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú wa tí ó sì ń ṣe làálàá. 17Mo láyọ̀ fún wíwá Stefana àti Fortunatu àti Akaiku, nítorí èyí tí ó kù nípá tí yín wọ́n ti fi kún un. 18Nítorí tí wọ́n tu ẹ̀mí mí lára àti tiyín: nítorí náà, ẹ máa gba irú àwọn ti ó rí bẹ́ẹ̀.

Ìkíni ìkẹyìn

1916.19: Ap 18.2; Ro 16.5.Àwọn ìjọ ni Asia kí í yín.

Akuila àti Priskilla kí í yín púpọ̀ nínú Olúwa, pẹ̀lú ìjọ tí ó wà ni ilé wọn.

2016.20: Ro 16.16.Gbogbo àwọn arákùnrin kí í yín.

Ẹ fi ìfẹnukonu mímọ́ kí ara yín.

2116.21: Kl 4.18; Ga 6.11; 2Tẹ 3.17.Ìkíni ti èmi Paulu, láti ọwọ́ èmi tìkára mi wá.

2216.22: Ro 9.3.Bí ẹnikẹ́ni kò bá ní ìfẹ́ Jesu Kristi Olúwa, jẹ́ kí ó dì ẹni ìfibú. Máa bọ Olúwa wa!

2316.23: Ro 16.20.Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa kí ó wà pẹ̀lú yín!

24Ìfẹ́ mi wá pẹ̀lú gbogbo yín nínú Kristi Jesu. Àmín.

Swedish Contemporary Bible

1 Korintierbrevet 16:1-24

Insamlingen till de troende i Jerusalem

1När det gäller insamlingen till de heliga, ska ni följa de instruktioner jag gav till församlingarna i Galatien16:1 Galatien var en romersk provins i nuvarande Turkiet.. 2Dagen efter sabbaten ska var och en ta en del av det han tjänat, så mycket han har råd med, och spara det, så att man inte börjar samla ihop det först när jag har kommit. 3När jag sedan kommer, ska jag skicka ut några lämpliga personer som ni utser och förse dem med brev, så att de kan resa till Jerusalem med gåvan. 4Men om det är bättre att jag också reser dit, då kan vi göra sällskap.

Paulus och hans medarbetares resplaner

5Jag planerar att resa genom Makedonien16:5 Makedonien var en romersk provins i nuvarande Grekland. Den låg norr om den provins där Korinth låg., och när jag har gjort det tänker jag komma till er. 6Antagligen stannar jag hos er ett tag, kanske hela vintern, och sedan kan ni hjälpa mig med det jag behöver för min fortsatta resa, vart det nu blir. 7Den här gången vill jag inte bara göra ett kort besök och sedan resa vidare, utan jag hoppas kunna stanna ett bra tag, om Herren tillåter det. 8Men jag stannar i Efesos till pingst, 9för här står en dörr öppen för mig till ett effektivt arbete just nu, även om det också finns många motståndare.

10Om Timotheos kommer till er, se då till att han kan känna sig lugn när han är hos er. Han arbetar för Herren precis som jag gör, 11så låt ingen se ner på honom. Hjälp honom sedan med att komma iväg i frid, så att han kan komma tillbaka till mig. Jag ser fram emot att få träffa honom, och det gör bröderna också. 12Vad det gäller vår bror Apollos, så uppmanade jag honom resa till er tillsammans med de andra, men han ansåg inte det var rätt tid just nu. Han kommer till er senare, när han får tillfälle.

Slutliga förmaningar och hälsningar

13Vaka över er själva, och se till att ni håller fast vid er tro. Var modiga och starka, 14och handla alltid i kärlek.

15Jag vill också be er om en sak, syskon. Ni vet ju att Stefanas och hans familj var de första i provinsen Achaia16:15 Achaia var en romersk provins i nuvarande Grekland. som började tro på Kristus. De ägnar sig nu åt att tjäna de heliga. 16Underordna er dessa människor, och även alla andra som jobbar hårt tillsammans med dem. 17Jag är glad över att Stefanas, Fortunatus och Achaikos har kommit till mig. Då behöver jag inte sakna er lika mycket. 18De har nämligen uppmuntrat mig på alla sätt, och er också. Sådana män ska ni verkligen sätta värde på.

19Församlingarna i provinsen Asien16:19 Provinsen Asien var en romersk provins i nuvarande Turkiet. hälsar till er. Aquila och Prisca och hela den församling som möts i deras hus hälsar hjärtligt till alla er i Herren. 20Alla de troende här hälsar till er. Hälsa varandra med en helig kyss.16:20 Se not till Rom 16:16.

21Här skriver jag, Paulus, min hälsning, med egen hand.

22Om någon inte älskar Herren, ska en förbannelse komma över honom. Marana ta!16:22 Arameiska för: Vår Herre, kom!

23Nåd från Herren Jesus åt er alla.

24Min kärlek är med er alla i Kristus Jesus.