ปฐมกาล 11 – TNCV & YCB

Thai New Contemporary Bible

ปฐมกาล 11:1-32

หอบาเบล

1ครั้งนั้นทั้งโลกใช้ภาษาเดียวกัน ใช้ถ้อยคำเหมือนกัน 2เมื่อมนุษย์ย้ายถิ่นฐานไปทางทิศตะวันออก11:2 หรือจากทิศตะวันออกหรือในทิศตะวันออก พวกเขาพบที่ราบในดินแดนชินาร์11:2 คือ บาบิโลน จึงตั้งหลักแหล่งอยู่ที่นั่น

3พวกเขาพูดกันว่า “มาเถิด ให้เราทำอิฐและเผาจนสุก” พวกเขาใช้อิฐแทนหินและใช้ยางมะตอยแทนปูน 4แล้วพวกเขาพูดว่า “มาเถิด ให้เราสร้างเมืองที่มีหอสูงขึ้นถึงฟ้าสำหรับพวกเรา เพื่อเราจะได้สร้างชื่อให้กับตนเองและไม่ต้องกระจายไปทั่วทั้งโลก”

5แต่องค์พระผู้เป็นเจ้าเสด็จลงมาเพื่อทอดพระเนตรเมืองและหอคอยซึ่งพวกเขากำลังสร้าง 6องค์พระผู้เป็นเจ้าตรัสว่า “คนเหล่านี้เป็นชนชาติเดียวกัน พูดภาษาเดียวกัน ยังริเริ่มทำงานได้ถึงเพียงนี้ ต่อไปถ้าเขาวางแผนจะทำอะไรก็จะทำได้ทุกอย่าง 7มาเถิด ให้เราลงไปทำให้เขามีภาษาสับสนแตกต่างกันออกไป เพื่อเขาจะได้ไม่เข้าใจกัน”

8ดังนั้นองค์พระผู้เป็นเจ้าจึงทรงทำให้พวกเขากระจัดกระจายจากที่นั่นออกไปทั่วทั้งโลก และพวกเขาก็หยุดสร้างเมืองนั้น 9ด้วยเหตุนี้เมืองนั้นจึงได้ชื่อว่าบาเบล11:9 คือ บาบิโลน คำว่าบาเบลมีเสียงคล้ายคำภาษาฮีบรูที่มีความหมายว่าสับสน เพราะที่นั่นเป็นที่ที่องค์พระผู้เป็นเจ้าทรงกระทำให้ภาษาของโลกสับสนแตกต่างกันออกไป องค์พระผู้เป็นเจ้าทรงทำให้พวกเขากระจัดกระจายไปอาศัยอยู่ทั่วทั้งโลก

จากเชมถึงอับราม

(ปฐก.10:21-31; 1พศด.1:17-27)

10นี่คือเรื่องราวเชื้อสายของเชม

สองปีหลังจากน้ำท่วม เมื่อเชมอายุได้ 100 ปีก็มีบุตรชาย11:10 ภาษาเดิมว่าได้เป็นบิดาของซึ่งคำว่าบิดาอาจจะมีความหมายว่าบรรพบุรุษเช่นเดียวกับข้อ 11-25ชื่ออารปัคชาด 11หลังจากนั้นเชมมีชีวิตต่อไปอีก 500 ปี และมีบุตรชายหญิงอีกหลายคน

12เมื่ออารปัคชาดอายุได้ 35 ปีก็มีบุตรชายชื่อเชลาห์ 13หลังจากนั้นเขามีชีวิตต่อไปอีก 403 ปี และมีบุตรชายหญิงอีกหลายคน11:13 ฉบับ LXX. ว่า35 ปี เขามีบุตรชื่อไคนัน 13หลังจากนั้นเขามีอายุต่อไปอีก 430 ปี มีบุตรชายหญิงอีกหลายคน แล้วเขาก็ตาย เมื่อไคนันมีอายุได้ 130 ปีเขามีบุตรชื่อเชลาห์ หลังจากนั้นเขามีชีวิตต่อไปอีก 330 ปี และมีบุตรชายหญิงอีกหลายคน (ดูลก.3:35-36 และเชิงอรรถของปฐก.10:24)

14เมื่อเชลาห์อายุได้ 30 ปีก็มีบุตรชายชื่อเอเบอร์ 15หลังจากนั้นเขามีชีวิตต่อไปอีก 403 ปี และมีบุตรชายหญิงอีกหลายคน

16เมื่อเอเบอร์อายุได้ 34 ปีก็มีบุตรชายชื่อเปเลก 17หลังจากนั้นเขามีชีวิตต่อไปอีก 430 ปี และมีบุตรชายหญิงอีกหลายคน

18เมื่อเปเลกอายุได้ 30 ปีก็มีบุตรชายชื่อเรอู 19หลังจากนั้นเขามีชีวิตต่อไปอีก 209 ปี และมีบุตรชายหญิงอีกหลายคน

20เมื่อเรอูอายุได้ 32 ปีก็มีบุตรชายชื่อเสรุก 21หลังจากนั้นเขามีชีวิตต่อไปอีก 207 ปี และมีบุตรชายหญิงอีกหลายคน

22เมื่อเสรุกอายุได้ 30 ปีก็มีบุตรชายชื่อนาโฮร์ 23หลังจากนั้นเขามีชีวิตต่อไปอีก 200 ปี และมีบุตรชายหญิงอีกหลายคน

24เมื่อนาโฮร์อายุได้ 29 ปีก็มีบุตรชายชื่อเทราห์ 25หลังจากนั้นเขามีชีวิตต่อไปอีก 119 ปี และมีบุตรชายหญิงอีกหลายคน

26หลังจากที่เทราห์อายุ 70 ปี เขาก็มีบุตรชายชื่ออับราม นาโฮร์ และฮาราน

27นี่คือเรื่องราวเชื้อสายของเทราห์

เทราห์มีบุตรชายชื่ออับราม นาโฮร์ และฮาราน ฮารานมีบุตรชายชื่อโลท 28ขณะที่เทราห์บิดาของเขายังมีชีวิตอยู่ ฮารานได้สิ้นชีวิตลงที่เมืองเออร์ของชาวเคลเดียซึ่งเป็นบ้านเกิดของเขา 29ทั้งอับรามและนาโฮร์แต่งงานมีครอบครัว ภรรยาของอับรามชื่อซาราย ภรรยาของนาโฮร์ชื่อมิลคาห์ ซึ่งเป็นบุตรีของฮารานผู้เป็นบิดาของทั้งมิลคาห์และอิสคาห์ 30นางซารายนั้นไม่มีบุตรเพราะเป็นหมัน

31เทราห์พาบุตรชายชื่ออับราม หลานชายชื่อโลทซึ่งเป็นบุตรชายของฮาราน และบุตรสะใภ้ชื่อซาราย ซึ่งเป็นภรรยาของอับรามบุตรชายของเขา ออกจากเมืองเออร์ของชาวเคลเดียเพื่อไปคานาอัน แต่เมื่อมาถึงเมืองฮารานก็ตั้งถิ่นฐานที่นั่น

32เทราห์มีชีวิตอยู่ 205 ปี แล้วเขาก็ตายที่เมืองฮาราน

Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn

Gẹnẹsisi 11:1-32

Ilé ìṣọ́ Babeli

1Lẹ́yìn náà, gbogbo àgbáyé sì ń sọ èdè kan ṣoṣo. 2Bí àwọn ènìyàn ṣe ń tẹ̀síwájú lọ sí ìhà ìlà-oòrùn, wọ́n rí pẹ̀tẹ́lẹ̀ kan ní ilẹ̀ Ṣinari,11.2 tí ó túmọ̀ sí, Babeli wọ́n sì tẹ̀dó síbẹ̀.

3Wọ́n sì wí fún ara wọn pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a mọ bíríkì kí a sì sún wọ́n jìnà.” Bíríkì ni wọ́n ń lò ní ipò òkúta, àti ọ̀dà ilẹ̀ tí wọn ń lò láti mú wọn papọ̀ dípò ẹfun (òkúta láìmù tí wọ́n fi ń ṣe símẹ́ńtì àti omi). 4Nígbà náà ni wọ́n wí pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a tẹ ìlú kan dó fún ara wa, kí a sì kọ́ ilé ìṣọ́ kan tí yóò kan ọ̀run, kí a ba à lè ní orúkọ,11.4 tí ó túmọ̀ sí, òkìkí kí a má sì tú káàkiri sórí gbogbo ilẹ̀ ayé.”

5Ṣùgbọ́n, Olúwa sọ̀kalẹ̀ láti wo ìlú àti ilé ìṣọ́ tí àwọn ènìyàn náà ń kọ́. 6Olúwa wí pé, “Bí àwọn ènìyàn bá ń jẹ́ ọ̀kan àti èdè kan tí wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe iṣẹ́ yìí, kò sí ohun tí wọ́n gbèrò tí wọn kò ní le ṣe yọrí. 7Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a sọ̀kalẹ̀ lọ, kí a da èdè wọn rú kí èdè wọn má ba à yé ara wọn mọ́.”

8Olúwa sì tú wọn ká sórí ilẹ̀ gbogbo, wọ́n sì ṣíwọ́ ìlú náà tí wọn ń tẹ̀dó. 9Ìdí èyí ni a fi pè é ní Babeli11.9 Èyí ní Babiloni; Babeli ni èdé Heberu tí a mọ̀ sí ìdàrúdàpọ̀. nítorí ní ibẹ̀ ni Olúwa ti da èdè gbogbo ayé rú. Olúwa tí sì tú àwọn ènìyàn ká sí gbogbo orí ilẹ̀ ayé.

Ìran Ṣemu tó fi dé ti Abramu

10Wọ̀nyí ni ìran Ṣemu.

Ọdún méjì lẹ́yìn ìkún omi, tí Ṣemu pé ọgọ́rùn-ún ọdún ni ó bí Arfakṣadi. 11Lẹ́yìn tí ó bí Arfakṣadi, Ṣemu tún wà láààyè fún ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ọdún (500), ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

12Nígbà tí Arfakṣadi pé ọdún márùndínlógójì ni ó bí Ṣela. 13Arfakṣadi sì wà láààyè fún ọdún mẹ́tàlénírinwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Ṣela, ó sì bí àwọn ọmọbìnrin àti àwọn ọmọkùnrin mìíràn.

14Nígbà tí Ṣela pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Eberi. 15Ṣela sì wà láààyè fún ọdún mẹ́tàlénírinwó (403) lẹ́yìn tí ó bí Eberi tán, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

16Eberi sì jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnlélọ́gbọ̀n, ó sì bí Pelegi. 17Eberi sì wà láààyè fún irinwó ọdún ó lé ọgbọ̀n (430) lẹ́yìn tí ó bí Pelegi, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

18Nígbà tí Pelegi pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Reu. 19Pelegi sì tún wà láààyè fún igba ọdún ó lé mẹ́sàn-án (209) lẹ́yìn tí ó bí Reu, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

20Nígbà tí Reu pé ọdún méjìlélọ́gbọ̀n ni ó bí Serugu. 21Reu tún wà láààyè lẹ́yìn tí ó bí Serugu fún igba ọdún ó lé méje (207), ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin mìíràn.

22Nígbà tí Serugu pé ọmọ ọgbọ̀n ọdún ni ó bí Nahori. 23Serugu sì wà láààyè fún igba ọdún lẹ́yìn tí ó bí Nahori, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

24Nígbà tí Nahori pé ọmọ ọdún mọ́kàndínlọ́gbọ̀n, ó bí Tẹra. 25Nahori sì wà láààyè fún ọdún mọ́kàn dín lọ́gọ́fà lẹ́yìn ìbí Tẹra, ó sì bí àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin mìíràn.

26Lẹ́yìn tí Tẹra pé ọmọ àádọ́rin ọdún ó bí Abramu, Nahori àti Harani.

Ìgbé ayé Abrahamu

27Wọ̀nyí ni ìran Tẹra.

Tẹra ni baba Abramu, Nahori àti Harani. Harani sì bí Lọti. 28Harani sì kú ṣáájú Tẹra baba rẹ̀ ní ilẹ̀ ìbí rẹ̀ ní Uri ti ilẹ̀ Kaldea. 29Abramu àti Nahori sì gbéyàwó. Orúkọ aya Abramu ni Sarai, nígbà tí aya Nahori ń jẹ́ Milka, tí ṣe ọmọ Harani. Harani ni ó bí Milka àti Iska. 30Sarai sì yàgàn, kò sì bímọ.

31Tẹra sì mú ọmọ rẹ̀ Abramu àti Lọti ọmọ Harani, ọmọ ọmọ rẹ̀, ó sì mú Sarai tí i ṣe aya ọmọ rẹ̀. Abramu pẹ̀lú gbogbo wọn sì jáde kúrò ní Uri ti Kaldea láti lọ sí ilẹ̀ Kenaani. Ṣùgbọ́n nígbà tí wọn dé Harani wọ́n tẹ̀dó síbẹ̀.

32Nígbà tí Tẹra pé ọmọ igba ọdún ó lé márùn-ún (205) ni ó kú ní Harani.