Filemonbrevet 1 – BPH & YCB

Bibelen på hverdagsdansk

Filemonbrevet 1:1-25

1Dette brev er fra Paulus, som sidder fængslet for Jesu Kristi skyld, og fra Timoteus, min medarbejder.

Kære Filemon, min ven og partner i tjenesten, 2hils Apfia2 Ordret: „søsteren Apfia”, formodentligt Filemons kone. og hils Arkippos, der kæmper for Herrens sag, ligesom vi gør. Hils også hele den menighed, der samles i dit hus. 3Nåde være med jer og fred fra Gud, vores Far, og Herren Jesus Kristus.

4Jeg takker altid Gud, når jeg beder for dig, kære Filemon. 5Jeg har jo hørt om din levende tro på Jesus, vores Herre, og om din kærlighed til ham og alle kristne. 6Det er min bøn, at det fællesskab om troen, som du er med i, må blive endnu mere effektivt i tjenesten for Kristus gennem en fuld forståelse af alt det gode, han har givet os del i.6 Teksten er vanskelig at fortolke og kan oversættes på flere måder. 7Jeg har hørt, hvordan du har været til stor hjælp og opmuntring for de kristne der, og det har opmuntret mig meget at høre om din kærlighed til dem. Det har virkelig givet mig en stor glæde.

8-9Fordi jeg kender din kærlighed, kommer jeg med en bøn til dig. Egentlig kunne jeg vel frimodigt i Kristi navn befale dig at gøre det, som bør gøres. Du ville utvivlsomt være lydig over for en gammel mand som mig, der oven i købet er fængslet for Kristi skyld. Men jeg vil hellere appellere til dit gode hjerte. 10Min bøn til dig angår Onesimos, som jeg har vundet for Herren, mens jeg har siddet i fangenskab her. Han er blevet som en søn for mig.

11Før i tiden var Onesimos11 Navnet Onesimos var almindeligt blandt slaver og betyder „en, der er til gavn”. ikke ligefrem til gavn for dig, men nu er han blevet til gavn for os begge to. 12Når jeg nu sender ham tilbage til dig, er det, som om jeg sender mit eget hjerte. 13Jeg ville gerne have beholdt ham her, for han har været mig til stor hjælp, mens jeg har siddet i fængsel på grund af mit budskab om Jesus. Du ville sikkert gerne selv have hjulpet mig, men det gjorde din slave så i stedet for. 14Alligevel vil jeg ikke beholde ham uden dit samtykke, for han er trods alt din slave. Jeg ønsker heller ikke at tvinge dig til at gøre en god gerning. Den slags skal være frivilligt. 15Måske var det nødvendigt, at du skulle undvære ham for en tid for netop at få ham tilbage for evigt, 16ikke kun som slave, men som noget langt bedre, en medkristen som er højt elsket, ikke mindst af mig. Men du vil også selv elske ham højere nu, da I ud over det daglige arbejdsfællesskab også har fællesskab i Herren.

17Hvis du virkelig betragter mig som partner i tjenesten, så tag imod ham, som du ville tage imod mig. 18Hvis han har gjort noget forkert eller skylder dig noget, så skriv det på min regning. 19Jeg vil betale det for ham. Det garanterer jeg for ved min egen underskrift. På den anden side kunne man jo egentlig også sige, at du på en måde skylder mig dit liv.

20Kære kristne ven, vil du ikke nok gøre mig den tjeneste? Giv mig den glæde for Kristi skyld! 21Jeg har skrevet det her brev i tillid til, at du vil gøre, hvad jeg beder dig om. Ja, jeg er overbevist om, at du ville gøre meget mere.

22Samtidig vil jeg også bede dig om at være parat til at tage imod mig som din gæst. Jeg regner nemlig med, at Gud vil svare på jeres bønner og give mig min frihed tilbage, så jeg kan besøge jer.

23Epafras sender jer mange hilsener. Han sidder også i fængsel her for troens skyld. 24Også mine medarbejdere Markus, Aristark, Demas og Lukas sender deres hilsener.

25Herren Jesu Kristi nåde være med jeres ånd!

Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn

Filemoni 1:1-25

Ìkíni

1Èmi Paulu, ẹni tí a fi sẹ́wọ̀n nítorí pé ó ń wàásù ìyìnrere Jesu Kristi àti Timotiu arákùnrin wa,

Sí Filemoni ọ̀rẹ́ wa ọ̀wọ́n àti alábáṣiṣẹ́ wa, 2sí Affia arábìnrin wa, sí Arkippu ẹni tó jẹ́ jagunjagun fún àgbélébùú náà àti sí ìjọ àwọn Kristiani tí ó ń pàdé nínú ilé rẹ:

33: Ro 1.7.Oore-ọ̀fẹ́ fún un yín àti àlàáfíà láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wa àti Jesu Kristi.

Ìdúpẹ́ àti àdúrà

44: Ro 1.8.Èmi máa ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nígbà tí mo bá rántí rẹ nínú àdúrà mi, 5nítorí mo ń gbọ́ nípa ìgbàgbọ́ rẹ nínú Jesu Olúwa àti nípa ìfẹ́ rẹ sí àwọn ènìyàn mímọ́. 6Èmi ń gbàdúrà pé, bí ìwọ ti ń ṣe alábápín nínú ìgbàgbọ́ rẹ pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn, pé kí ìgbàgbọ́ náà lè mú ọkàn wọn dúró gbọingbọin, gẹ́gẹ́ bí wọn ti rí àwọn ọ̀rọ̀ ohun rere tí ó ń bẹ nínú ayé rẹ, èyí tí ó ti ọ̀dọ̀ Kristi wá. 7Ìfẹ́ rẹ ti fún mi ní ayọ̀ púpọ̀ àti ìgboyà, nítorí ìwọ, arákùnrin ti tu ọkàn àwọn ènìyàn mímọ́ lára.

Paulu bẹ̀bẹ̀ fún Onesimu

8Nítorí náà, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé nínú Kristi mo ní ìgboyà púpọ̀ láti pàṣẹ ohun ti ó yẹ kí ó ṣe fún ọ, 9síbẹ̀ nítorí ìfẹ́ èmí kúkú bẹ̀ ọ́. Èmi gẹ́gẹ́ bí Paulu, arúgbó, àti nísinsin yìí òǹdè Jesu Kristi. 1010: Kl 4.9.Èmí bẹ̀ ọ́ nítorí ọmọ mi Onesimu, ẹni tí ó di ọmọ nígbà tí mo wà nínú ìdè. 11Nígbà kan rí, kò wúlò fún ọ, ṣùgbọ́n ní báyìí, ó ti wúlò fún ọ àti fún èmi pàápàá.

12Èmi rán an nísinsin yìí, àní ẹni ọkàn mi padà sí ọ̀dọ̀ rẹ. 13Èmi ìbá fẹ́ láti dá a dúró sọ́dọ̀ mi níhìn-ín, kí ó ba à dípò rẹ láti máa ràn mí lọ́wọ́ nígbà tí mo wà nínú ìdè nítorí ìyìnrere 14ṣùgbọ́n èmi kò fẹ́ ṣe bẹ́ẹ̀ rárá láìgba ìyọ̀ǹda ní ọwọ́ rẹ, kí oore tí ìwọ bá ṣe má ba à jẹ́ ìfipámúniṣe bí kò ṣe ìfìfẹ́ṣe. 15Bóyá ìdí rẹ̀ tí òun fi yẹra kúrò lọ́dọ̀ rẹ fún ìgbà díẹ̀ ni pé kí ìwọ kí ó lè gbà á padà sọ́dọ̀ títí láé. 16Kì í wá ṣe bí ẹrú mọ́, ṣùgbọ́n bí ẹni ti ó sàn ju ẹrú lọ, gẹ́gẹ́ bí arákùnrin. Ó ṣọ̀wọ́n fún mi jọjọ, ṣùgbọ́n ó ṣọ̀wọ́n fún ọ jù nípa ti ara àti gẹ́gẹ́ bí arákùnrin nínú Olúwa.

17Nítorí náà bí ìwọ bá kà mí sí ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, tẹ́wọ́ gbà á bí ìwọ yóò ti tẹ́wọ́ gbà mí. 18Bí ó bá ti ṣe ọ́ ní ibi kan tàbí jẹ ọ́ ní gbèsè ohun kan, kà á sí mi lọ́rùn. 19Èmi Paulu, ni mo fi ọwọ́ ara mi kọ ìwé yìí; èmi yóò san án padà láì tilẹ̀ ní í sọ nípa pé ìwọ pàápàá jẹ mi ní gbèsè ara rẹ. 20Èmi ń fẹ́ arákùnrin, pé kí èmi kí ó lè ni àǹfààní kan láti ọ̀dọ̀ rẹ nínú Olúwa; fi ayọ̀ rẹ kún ọkàn mi nínú Kristi. 21Ìgbẹ́kẹ̀lé ti mo ní pé ìwọ yóò gbọ́rọ̀, ni mo fi kọ ìwé yìí ránṣẹ́ sí ọ. Mo mọ̀ dájú pé ìwọ yóò ṣe ju bí mo ti béèrè lọ.

22Ó ku ohun kan, ṣe ìtọ́jú iyàrá àlejò rẹ sílẹ̀ fún mi, nítorí mo ní ìgbàgbọ́ pé a óò tú mi sílẹ̀ fún yín ní ìdáhùn sí àdúrà yín.

23Epafira, òǹdè ẹlẹgbẹ́ mi nínú Kristi Jesu kí ọ. 2424: Ap 12.12,25; 13.13; 15.37-39; Kl 4.10; Ap 19.29; 27.2; Kl 4.10; Kl 4.14; 2Tm 4.10; Kl 4.14; 2Tm 4.11.Marku kí ọ pẹ̀lú Aristarku, Dema àti Luku, àwọn alábáṣiṣẹ́ mi.

25Kí oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa wa wà pẹ̀lú ẹ̀mí yín.