วิวรณ์ 15 – TNCV & YCB

Thai New Contemporary Bible

วิวรณ์ 15:1-8

ทูตสวรรค์เจ็ดองค์กับวิบัติทั้งเจ็ด

1ข้าพเจ้าเห็นหมายสำคัญอันอัศจรรย์และยิ่งใหญ่อีกอย่างในสวรรค์คือ ทูตสวรรค์เจ็ดองค์กับวิบัติทั้งเจ็ดอันเป็นภัยพิบัติครั้งสุดท้ายเพราะพระพิโรธของพระเจ้าสิ้นสุดลงที่ภัยพิบัติเหล่านี้ 2ข้าพเจ้าแลเห็นสิ่งหนึ่งคล้ายทะเลแก้วปนไฟ บรรดาผู้มีชัยชนะเหนือสัตว์ร้ายกับรูปจำลองและหมายเลขประจำชื่อของมันยืนอยู่ข้างๆ ทะเลนั้น เขาทั้งหลายถือพิณซึ่งพระเจ้าประทาน 3และขับร้องบทเพลงของโมเสสผู้รับใช้ของพระเจ้าและบทเพลงของพระเมษโปดกว่า

“ข้าแต่องค์พระผู้เป็นเจ้า พระเจ้าผู้ทรงฤทธิ์

พระราชกิจของพระองค์ยิ่งใหญ่และมหัศจรรย์ยิ่งนัก

ข้าแต่องค์ราชันของทุกยุคสมัย

วิถีของพระองค์ล้วนเที่ยงธรรมและเที่ยงแท้

4ข้าแต่องค์พระผู้เป็นเจ้า ใครเล่าจะไม่เกรงกลัวพระองค์

และไม่เทิดทูนพระนามของพระองค์

เพราะพระองค์แต่ผู้เดียวทรงบริสุทธิ์

มวลประชาชาติจะเข้ามา

และกราบนมัสการต่อหน้าพระองค์

เพราะกิจอันชอบธรรมของพระองค์เป็นที่ประจักษ์แล้ว”

5หลังจากนั้นข้าพเจ้าเห็นพระวิหารในสวรรค์เปิดออก พระวิหารนั้นคือพลับพลาแห่งสักขีพยาน 6ทูตสวรรค์เจ็ดองค์ที่ถือภัยพิบัติทั้งเจ็ดออกมาจากพระวิหาร นุ่งห่มผ้าลินินสะอาดสุกใส คาดแถบทองคำที่อก 7แล้วหนึ่งในสิ่งมีชีวิตทั้งสี่หยิบขันทองคำเจ็ดใบซึ่งเต็มด้วยพระพิโรธของพระเจ้าผู้ทรงพระชนม์อยู่ตลอดกาลส่งให้ทูตสวรรค์ทั้งเจ็ด 8และแล้วควันจากพระเกียรติสิริและเดชานุภาพของพระเจ้าก็ปกคลุมไปทั่วพระวิหาร ไม่มีผู้ใดเข้าไปในพระวิหารได้จนกว่าภัยพิบัติทั้งเจ็ดจากทูตสวรรค์เจ็ดองค์จะเสร็จสมบูรณ์

Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn

Ìfihàn 15:1-8

Angẹli méje pẹ̀lú ìyọnu méje

115.1: Le 26.21.Mo sì rí ààmì mìíràn ní ọ̀run tí ó tóbi tí ó sì ya ni lẹ́nu, àwọn angẹli méje tí ó ni àwọn ìyọnu méje ìkẹyìn, nítorí nínú wọn ni ìbínú Ọlọ́run dé òpin. 2Mo sì rí bí ẹni pé, Òkun dígí tí o dàpọ̀ pẹ̀lú iná: àwọn tí ó sì dúró lórí Òkun dígí yìí jẹ́ àwọn ti wọ́n ṣẹ́gun ẹranko náà, àti àwòrán rẹ̀, àti ààmì rẹ̀ àti nọ́mbà orúkọ rẹ̀, wọn ní ohun èlò orin Ọlọ́run. 315.3: Ek 15.1; Sm 145.17.Wọ́n sì ń kọ orin ti Mose, ìránṣẹ́ Ọlọ́run, àti orin ti Ọ̀dọ́-Àgùntàn, wí pé:

“Títóbi àti ìyanu ni àwọn iṣẹ́ rẹ,

Olúwa Ọlọ́run Olódùmarè;

òdodo àti òtítọ́ ni ọ̀nà rẹ̀,

ìwọ ọba àwọn orílẹ̀-èdè.

415.4: Jr 10.7; Sm 86.9-10.Ta ni kì yóò bẹ̀rù, Olúwa,

tí kì yóò sì fi ògo fún orúkọ rẹ̀?

Nítorí ìwọ nìkan ṣoṣo ni mímọ́.

Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ni yóò sì wá,

ti yóò sì foríbalẹ̀ níwájú rẹ,

nítorí a ti fi ìdájọ́ rẹ hàn.”

515.5: Ek 40.34.Lẹ́yìn náà mo sì wo, sì kíyèsi i, a ṣí tẹmpili àgọ́ ẹ̀rí ní ọ̀run sílẹ̀; 6àwọn angẹli méje náà sì ti inú tẹmpili jáde wá, wọ́n ni ìyọnu méje náà, a wọ̀ wọ́n ní aṣọ ọ̀gbọ̀ funfun ti ń dán, a sì fi àmùrè wúrà dìwọ́n ni oókan àyà. 7Àti ọ̀kan nínú àwọn ẹ̀dá alààyè mẹ́rin náà fi ìgò wúrà méje fún àwọn angẹli méje náà, tí ó kún fún ìbínú Ọlọ́run, ẹni tí ń bẹ láààyè láé àti láéláé. 8Tẹmpili náà sì kún fún èéfín láti inú ògo Ọlọ́run àti agbára rẹ̀ wá; ẹnikẹ́ni kò sì lè wọ inú tẹmpili náà lọ títí a fi mú ìyọnu méjèèje àwọn angẹli méje náà ṣẹ.