Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn

Saamu 117

1Ẹ yin Olúwa, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;
    ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn.
Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa,
    àti òtítọ́ Olúwa dúró láéláé.

Ẹ yin Olúwa!

Saral Hindi Bible

Este capítulo no está disponible momentáneamente. Por favor intente nuevamente luego.